Alagbede Orin gege bii oruko re tun ti ra Eran odun fawon eeyan gege bi ise re lodoodun,bo se ra Eran lo tun ra iresi,bee lo fowo si fun gbogbo won ti pupo ninu won si ti n ro ojo adura ranse si omo Okunola lasiko yii.
Sugbon Oro ko ri bee lodo awon omoose oba asakasa iyen Alaaji Abass Akande Obesere pelu bi ko se gbe ipe awon omoose ti ko si fun won lowo rara ti Inu awon omoose e ko si fun si i rara.
Ju gbogbo e lo Oba Orin to n se daadaa lorile ede America ti dun awon omoose e ninu ti pupo ninu awon Ololufe e ti n so pe oun gan an lo n sebi oba laarin awon olorin Fuji lasiko yii.


No comments:
Post a Comment