Inu ibanuje ni pupo ninu awon olorin isilaamu wa bayii pelu bi okan ninu won to tun je purodusa se je ipe Olorun leyin aisan olojo pipe,Ariyo Producer to maa n gbe Orin Fuji ati ti isilaamu jade ni iku ti pa oju e de bayii.
Epe nipinle Eko ni won sin si ti opo awon ololufe Orin isilaamu si to n daro Ariyo Producer titi di asiko yii

No comments:
Post a Comment