Agbegbe Bwari ni Abuja nisele naa ti sele lose to koja nigba ti ojo nla kan to,asiko yii ni egbon Faisal ti so pe ko lo tu Eran kuro ninu ojo sugbon to je pe nise ni ogbara ojo naa gbe Faisal lo.
Wednesday, October 26, 2022
Home
Isele Kayeefi
Ikunle abiamo o!Nibi to ti fe lo doola emi Eran ni ogbara ojo ti gbe Faisal lo ni Abuja
Ikunle abiamo o!Nibi to ti fe lo doola emi Eran ni ogbara ojo ti gbe Faisal lo ni Abuja
Ẹka Iroyin
# Isele Kayeefi
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Isele Kayeefi
Labels:
Isele Kayeefi
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment