O n rugbo bo! Won ni Olori Ashley ati Olori Tobi n ja laafin Ooni,ibi aye igbokosi lo dija sile - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, October 24, 2022

O n rugbo bo! Won ni Olori Ashley ati Olori Tobi n ja laafin Ooni,ibi aye igbokosi lo dija sile

Gbas Gbas ti n sele laafin Ooni Ile Ife pelu bi awon oniroyin ayelujara ti n gbe iroyin kiri pe, Olori meji iyen Olori Ashley ati Olori Tobi n ja Koda a gbo pe Olori Tobi ko igbaju igbamu bo Olori Ashley nitori aaye igbokosi.
Erin lawon to gbo si Oro naa n rin pe, orisirisi nnkan ni yoo maa sele laafin oonirisa to ti fe iyawo to le ni marun un bayii.


No comments:

Post a Comment

Pages