Oba Ajido iyen oba Adamson ko igbaju bo Oloye re to n je Oloye Micheal - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, October 12, 2022

Oba Ajido iyen oba Adamson ko igbaju bo Oloye re to n je Oloye Micheal

A fi bi eni n wo sinima ni Oro naa ri ni agbegbe Ajido ni Badagry nigba ti oba Ajido iyen oba Adamson ko ese bo okan ninu awon Oloye re lasiko ti won n sepade lowo,a gbo pe,aawo kekere kan lo sele laarin won ni oba naa ba ko igbaju igbamu fun Oloye naa


No comments:

Post a Comment

Pages