O sele!Saheed Osupa fagba han Obesere nidi oselu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Sunday, January 15, 2023

O sele!Saheed Osupa fagba han Obesere nidi oselu

O dabi enipe oruko lo n ro Oba Orin Iyen Alaaji Saheed Osupa nitori nise ni Osupa re n tan Kari aye lasiko yii,nitori bo se gba ipo mo oba asakasa iyen Alaaji Abass Akande Obesere lowo .
Gege bi awon to gbe iroyin naa si wa leti se so pe, Obesere gan an ni egbe oselu PDP maa n lo lasiko ipolongo ibo sugbon nitori iwa ojukokoro ati ainitelorun lo mu omorapala lo korin fawon egbe oselu APC lasiko kan ti a gbo pe iwa yii ko dun mo awon egbe naa ninu.
Latigba naa ni ko ti si egbe kankan to pe Obesere sode ipolongo ibo mo,bi Oluaye iyen Alaaji Wasiu Ayinde se n Jaye oba ninu egbe oselu APC ni oba Orin naa se n pase lasiko yii ninu egbe oselu PDP Koda a gbo pe osuba 'O kare lai ni Gomina ipinle Oyo iyen Ogbeni Seyi Makinde gbe fun oba Orin nitori ise takuntakun to se nibadan fun bii ose meji gbako lati polongo ibo fun egbe oselu PDP


No comments:

Post a Comment

Pages