Odu ni Ogbeni Aremu je laarin awon akoroyin nigboro ilu Eko ati agbegbe re,yato si pe o tun je okan ninu awon Manija elere Fuji nla nni iyen Alaaji Abass Akande Obesere,Aremu tun ni oludari ileese Arems Entertainment ati 1st Eleven Naija
Ose to koja lo ba akoroyin wa soro pe,kawon eeyan jade lati lo dibo ki won le gbe asaaju gidi ti won fe sipo,o so pe gbigba owo riba ka to dibo ko dara,bee lo dara lati mo pe ibo wa lo le mu ojo ola rere wa fawon omo wa.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment