Okiki Bright fe gbe Orin ti yoo milu titi jade'Nigeria' ni akole re - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, February 6, 2023

Okiki Bright fe gbe Orin ti yoo milu titi jade'Nigeria' ni akole re

Odu ni Ogbeni Okiki Bright nidi ise Orin ,ki n se aimo fun gbogbo awon Ololufe Orin Fuji ati Orin takasufe,Ni bayii Okiki Bright ti so pe asiko tito lati gbe Orin tuntun ti akole re n je 'Nigeria'jade bayii pelu ipo ti Orile ede wa wa lasiko yii
Eja mejo otooto lo wa ninu awon Orin naa ,ti too si wulo fun tomode tagba beeni o je Orin ti ko se e ma ni ninu Ile nitori ojo ola Orile ede yii.
Ju gbogbo e lo, Ogbeni Okiki Bright ti so pe kawon Ololufe oun maa reti awo Orin naa,boya eyin fe pe Okiki Bright sode ere nomba re ni yii 08082024957


No comments:

Post a Comment

Pages