Awon kan ti sekupa kanselo kan ni Ibadan lojo toside, adugbo Ile tuntun nitosi Oluyoro Academy ni won ti pa a,topo omo egbe oselu PDP si tun farapa
Ninu iroyin mi in la tun ti gbo pe,awon kan Dena oko Gomina ElRufai tipinle Kaduna,adugbo Ruwa nitosi Igabi ni won ti Dena de oko re
A tun gbo pe,awon iko Olopaa kan seesi yinbon fun okunrin kan tiyawo e sese bimo a gbo pe okunrin yii wa ninu ogba Ile re,nigba tawon Olopaa yii deede wonu ogba naa ti won si yinbon fun un lasiko ti won n Le awon adigunjale kan ni adugbo Idemili nipinle Anambra.

No comments:
Post a Comment