Opo idile lo ti padanu eeyan won ninu isele ijamba oko to waye lagbegbe Ikeja nilu Eko lojo toside yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, March 9, 2023

Opo idile lo ti padanu eeyan won ninu isele ijamba oko to waye lagbegbe Ikeja nilu Eko lojo toside yii


A gbo pe ,oko ijoba Brt fe sare koja loju irin sugbon ti oko ojurin(train) ko lu u,emi opo eeyan lo ba isele naa lo.Gomina ipinle Eko iyen Ogbeni Sanwoolu fi aidunnu re han lori isele naa

No comments:

Post a Comment

Pages