Api baide tuuu yuuu baba ati omo e ,emi eyin mejeeji yoo se opo odun laye ninu alaafia ati ifokanbale,e Jaye Ori yin jare ota yin lo ni ibanuje
Gbogbo ojo kefa osu kerin ni ayeye ojo ibi gbajumo Sheik nni iyen Alaaji Iyanda Adekunle Ajibade Akewusola Olorun nidahun adura,ohun to tun wa je ki ojo yii yato nigbesi aye Alaaji Akewusola ni pe ojo kan nan ni oun ati akobi re iyen Alaaja Sofiat n se ojo ibi .

No comments:
Post a Comment