Omooba Adeyemo niroyin gba igboro pe oun naa tun ti lo sode Orun,asiko tawon oseretiata n mura adura ojo mejo Oloogbe Murphy Afolabi ni omooba Adeyemo naa seenji adiresi,aisan kidinrin to ti n ba Omo bibi ila orangun ja latojo pipe lo pada gba emi e
Olorun yoo ba wa dawo ibi duro,Amin
You are doing well my dear sister.
ReplyDelete