Iyawo Oba Ara wa dupe lowo awon to wa Lori ijoko lojo naa fun ife ti won ni si oun atoko e,bee lo dupe lowo oko e pe lati bii odun mesan an seyin ni erongba ati ni ileewe ti wa lokan oun nitori ti oun nife sawon omode
Wolii ijo won ,wolii Jeremiah Okikiola lo ba won si ileewe yii.Ohun to wa je ki Inu opo awon to wa nibe lojo naa tun dun ni pe olorin isilaamu toruko re n je Hawa Omo Ariyo wa lara awon olorin to forin da awon eeyan laraya,to tumo si pe,ife ti wa laarin awon olorin isilaamu ati Kristeni.
No comments:
Post a Comment