Won ti sinku Oloogbe Murphy Afolabi,omije n pe omije ran nise - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, May 15, 2023

Won ti sinku Oloogbe Murphy Afolabi,omije n pe omije ran nise


Ilu ikorodu nipinle Eko ninu Ile Oloogbe to n ko lowo ni won sinku e si ,ti eeyan ba je Ori ahun to ba de ibi eto isinku naa ,yoo bu Omi ekun mu ni
Adura wa ni pe,ki Olorun te Oloogbe Murphy Adewale Afolabi si Afefe rere

No comments:

Post a Comment

Pages