Aduke Gold ti pada soro sita nipa Orin Aboruboye ti won so pe agba oje olorin emi nni iyen Tope Alabi ko.
Aduke so pe,Orin oun ni sugbon Tope kan na oun ko die jade sita lasiko tawon pads Lori oke baba Abiye'ni Ede
Aduke wa dupe lowo Oga e nidi ise Orin emi iyen Tope Alabi pe,oun lo je ki Orin naa migboro titi gan an Koda koun to gbe awo Orin naa jade
Bee lo n be awon ololufe Orin emi pe, gbolohun Aboruboye yii ki n se gbolohun awon 'Alawo rara nitori ebo riru gan an wa ninu bibeli,beeni ki awon eeyan Mase foju alawo wo Oga oun Tope Alabi mo,o so pe Ona tawon gba lo Yoruba Nini Orin naa lo je kopo eeyan ro pe gbolohun Awo ni

No comments:
Post a Comment