Won so pe,Tope Alabi ti di iyalorisa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, June 23, 2023

Won so pe,Tope Alabi ti di iyalorisa


Nitori ti akorin emi nni,Tope Alabi korin pe,aboru loun ati pe oun ti di Aboru ati aboye lawon ololufe e kan ti wa n so pe, Obinrin naa ti n bo orisa ni
A gbo pe opo awon onigbagbo mi in ti n so Kiri pe,ko ye ki Tope Fi Aboru ati aboye korin igbagbo nitori gbolohun awon 'Alawo' ni

No comments:

Post a Comment

Pages