Mo maa dupo Aare Orile ede yii ninu eto idibo to n bo -Onorebu Oguntoyinbo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, July 16, 2023

Mo maa dupo Aare Orile ede yii ninu eto idibo to n bo -Onorebu Oguntoyinbo


Ti a ba n soro nipa onisowo ati oloselu to dangajia nipinle Ogun lasiko yii,odu ni Onorebu Ajadi Oguntoyinbo ki n se aimo fun oloko rara,Ogbeni naa ni oludari ileese Bullion Go-Neat Global Ltd iyen ileese to n se ohun mimu 'Coco Samba',yato si pe okunrin yii nileese to n pese ise fawon Odo nipinle re,oun tun lo jade du ipo Gomina labe Asia egbe oselu Nnpp ninu eto idibo to koja.
Odomode oloselu yii to tun je asoju fawon Odo orile ede yii gba egbe Akoroyin l'ede Yoruba lalejo si ofiisi re ni ibafo ipinle Ogun lose to koja,to si so opo Oro,ojo naa lo salaye pe,odale ati ojelu ni Oloye Olamiposi Oginni je pelu bo se ta oun ni idibo sipo Gomina ku ose kan
O so pe Oloye Oginni kede pe,egbe oselu Nnpp ti darapo mo egbe oselu PDP lai so fun oun rara,o salaye pe o dun oun gidi ,bee loun kabamo pe,oun pade Oloye Oginni ninu irin Ajo aye oun nidi oselu
O tun ti wa so pe,oun maa dupo Aare Orile ede yii ninu eto idibo to n bo,bee lo tun Fi idunnu re han si Aare Tinubu to si so pe oun setan lati ba a sise papo lasiko yii nitori agba oselu ni baba naa

No comments:

Post a Comment

Pages