Nitori Oro Yeye Ajesikemi to Fe sodun egbe nilu Ilorin lo mu Ojogbon Soyinka ko leta si olola Sulugambari ti Ilorin pe,ko Dara bi awon egbe musulumi se n dunkooko mo obinrin naa ati pe ko SI orile ede ti won ko ti n se odun Egbe
Sulugambari naa ti wa so pe,ilu alaafia ni Ilorin ,bee ni oun ko Fe ki ija waye loun se pase pe ki Yeye Ajesikemi mase se odun Egbe laarin ilu Ilorin

No comments:
Post a Comment