Oloogbe Ayinla Omowura ranse sawon ololufe re latorun o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, July 19, 2023

Oloogbe Ayinla Omowura ranse sawon ololufe re latorun o


Omo Oloogbe Ayinla Omowura iyen ,Alimot Omowura ti pe gbogbo awon ololufe baba e lati wa Fi ijoko ye e si,lojo kokanlelogbon osu kejo odun yii ni Gbogan nla to dojuko kaampu awon agunbaniro to wa ni Iyana ipaja nipinle Eko
Oganla Fuji iyen Alaaji Wasiu Alabi Pasuma ati Baba Oko,Alaaji Sefiu Also atawon olorin Fuji mi in yoo dalubole lojo naa
Ankara ati fila pelu gele lawon ololufe Alimo Omowura yoo Fi wole sinu Gbogan naa,lasiko to n ba tojubole soro ni Alimo Omowura ti so pe,nitori awon ololufe Orin baba oun ati pe oun ko Fe ki oruko naa pare pelu bi oruko rere se dara ju wura ati fadaka lo
O ti wa so pe jije ati mimu yoo sele nibi ayeye yii beeni ifami eye da awon ololufe oloogbe Omowura yoo waye pelu.

No comments:

Post a Comment

Pages