Olorunseun o!Toyin Abraham Ajeyemi ati Adeniyi Johnson ti Pari ija olojo pipe won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, July 19, 2023

Olorunseun o!Toyin Abraham Ajeyemi ati Adeniyi Johnson ti Pari ija olojo pipe won


Ibi ikojade fiimu Odunlade Adekola lawon mejeeji yii ti Pari ija,lasiko ti Toyin de sibi ayeye ikojade fiimu 'Sango 'ti Odunlade ko ni Toyin ti ki Niyi pe,Ori e da lorun e,ni Niyi naa ba da a lohun pe,'Se o wa?
Idaniloju wa pe ,awon mejeeji ti won ti je ololufe meji ri yii si maa kopa papo ninu fiimu kan nan bayii

No comments:

Post a Comment

Pages