Gomina ipinle Oyo ta oba Orin Osupa lebun oko bogini - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, August 21, 2023

Gomina ipinle Oyo ta oba Orin Osupa lebun oko bogini

Aaro ojo monde iyen ojo aje ose yii gan an ni Gomina ipinle Oyo, Ogbeni Seyi Makinde ta Oba Fuji Alaaji Saheed Osupa l'ebun oko bogini ti owo re le ni ogota milioonu.
Alagbede Orin Fi idunnu re han bee lo dupe lowo Gomina fun Ebun nla naa
Ojo die leyin ti Osupa de lati Orile ede America ni Gomina Makinde Fi Ebun nla yii da a Lola.Oba Orin emi re a lo o lagbara Olorun 


No comments:

Post a Comment

Pages