Nibi adura ojo mejo baba Bobrisky,awon Aafa so pe, Olorun yoo pese Omo fun un laipe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Thursday, August 24, 2023

Nibi adura ojo mejo baba Bobrisky,awon Aafa so pe, Olorun yoo pese Omo fun un laipe


Adura kan tawon Aafa gba fun Idris Okuneye iyen omokunrin to maa n se bii Obinrin nni, Bobrisky ni won ti sadura pe, Olorun yoo pese Omo to maa toju oun naa fun un laipe,sugbon tawon to gbo ohun ti awon Aafa yii so ti n ju bombu Oro ranse pe, onijekuje ni Aafa naa

No comments:

Post a Comment

Pages