Ayeye ọdun ifa oloye Ọpẹifa Toriọla yoo waye ni sannde ọsẹ yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, November 28, 2023

Ayeye ọdun ifa oloye Ọpẹifa Toriọla yoo waye ni sannde ọsẹ yii


Gbogbo adugbo Rafco nitosi MAO ni Alagbado ipinlẹ Eko yoo mi titi lọjọ sannde iyẹn ọjọ kẹta oṣu kejila ọdun yii
Oloye Toriọla yoo gbalejo awọn eeyan gidi sibi ayẹyẹ ọdun ifa ẹ,Alaaji Sule Alao Malaika ni yoo dalubolẹ lọjọ naa nigbati Okele,Baraka ati Koyokoyo yoo tukọ eto.Boya ẹ ni ibeere tabi ẹ fẹ beere nipa igbesi aye yin,e pe oloye Ọpeifa si 08034085454

No comments:

Post a Comment

Pages