Adugbo ỌbaAra nilu Ikorodu gbalejo awọn eeyan pataki lọjọ tọside iyẹn ọjọ ọjọbọ ọsẹ to kọja,nibi ti olorin juju nni ẹfanjẹliisi Rotimi Onimọlẹ ti ṣọdun fawọn ololufẹ,ohun to wa jẹ ki ọjọ naa tun dun yatọ ni bi ọpọ awọn ololufẹ atawọn ọrẹ Obaara naa ṣe fẹbun awọọdu da Obaara naa lọla lati mọ riri rẹ ni eyi to tumọ si pe,ipa ribiribi ni olorin ẹmi naa n ko nigbesi aye awọn naa.
Saturday, December 23, 2023
Efanjẹlisi Rotimi ỌbaAra ṣ'ọdun fawọn ololufẹ.
Adugbo ỌbaAra nilu Ikorodu gbalejo awọn eeyan pataki lọjọ tọside iyẹn ọjọ ọjọbọ ọsẹ to kọja,nibi ti olorin juju nni ẹfanjẹliisi Rotimi Onimọlẹ ti ṣọdun fawọn ololufẹ,ohun to wa jẹ ki ọjọ naa tun dun yatọ ni bi ọpọ awọn ololufẹ atawọn ọrẹ Obaara naa ṣe fẹbun awọọdu da Obaara naa lọla lati mọ riri rẹ ni eyi to tumọ si pe,ipa ribiribi ni olorin ẹmi naa n ko nigbesi aye awọn naa.
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment