Ọlọpaa lawọn mejeeji,ọdaran torukọ ẹ n jẹ Akere ni wọn fẹ lọ mu ṣugbọn ti olọọpa to n jẹNelson fibọn pa ikeji ẹ to n jẹ Monday,oun ati iya Monday gbiyanju lati gbe e lọ sile iwosan ṣugbọn ti epo tan ninu ọkọ to si mu ki ọgbẹni Monday ku sinu ọkọ,a gbọ pe oju ẹsẹ ni ọgbẹni Nelson yinbọn fun ara ẹ toun naa si ku,wọn ti gbe oku awọn mejeeji lọ sile igbokupamọ si kan nipinlẹ Rivers .Grace to je agbenuso awon olopaa nipinle naa fidi isele yii mule
Wednesday, December 20, 2023
Nelson para ẹ nitori to ṣeeṣi gbẹmi ọrẹ ẹ nipinlẹ Rivers
Ọlọpaa lawọn mejeeji,ọdaran torukọ ẹ n jẹ Akere ni wọn fẹ lọ mu ṣugbọn ti olọọpa to n jẹNelson fibọn pa ikeji ẹ to n jẹ Monday,oun ati iya Monday gbiyanju lati gbe e lọ sile iwosan ṣugbọn ti epo tan ninu ọkọ to si mu ki ọgbẹni Monday ku sinu ọkọ,a gbọ pe oju ẹsẹ ni ọgbẹni Nelson yinbọn fun ara ẹ toun naa si ku,wọn ti gbe oku awọn mejeeji lọ sile igbokupamọ si kan nipinlẹ Rivers .Grace to je agbenuso awon olopaa nipinle naa fidi isele yii mule
Ẹka Iroyin
# Isele Kayeefi
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Isele Kayeefi
Labels:
Isele Kayeefi
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment