Ọpẹ o!Alaaji Wasiu Buaya di ọba iṣegun ifọ lapapọ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, December 30, 2023

Ọpẹ o!Alaaji Wasiu Buaya di ọba iṣegun ifọ lapapọ


Alaaji Buaya ti n fi asiko yii dupẹ lọwọ gomina ipinlẹ Ogun,ọmọọba Abiọdun,alaga ijọba ibilẹ ifọ,awọn ẹgbẹ oniṣegun fun aduroti wọn lasiko to di ọbaaṣegun ibilẹ ifọ lapapọ o ti wa sọ pe,igba ọtun ti de sinu ẹgbẹ oniṣegun ni ijoba ibilẹ oun bayii nitori ọpọ nnkan lawọn egbẹ yoo gbadun labẹ iṣakoso oun

No comments:

Post a Comment

Pages