Ode ere odun ọjọ kinni ọdun Wasiu Ayinde,ọmọọṣẹ ẹ s'oko ọrọ si Aarẹ Tinubu,o ṣoju Atoriṣe olorin ẹmi - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, January 6, 2024

Ode ere odun ọjọ kinni ọdun Wasiu Ayinde,ọmọọṣẹ ẹ s'oko ọrọ si Aarẹ Tinubu,o ṣoju Atoriṣe olorin ẹmi


Ọjọ kinni ọdun ni Oluaye fuji ,Alaaji Wasiu Ayinde ṣere ọdun ṣugbọn ti manija ẹ,ọnọrebu Bayọ Ọlaṣọju ko jẹ kawọn oniroyin wọle to si jẹ pe awọn ọmọge lo n gba laye sinu gbọgan
ọmọọṣẹ Oluaye kan to n jẹ king Mabo lo tun sọrọ si akoroyin ileeṣẹ iwe iroyin Aarẹ Tinubu kan lasiko ti Atoriṣe olorin ẹmi fẹ mu akoroyin naa wọle ti king Mabo si sọ pe oun korira Aarẹ oun ko le gba ki akọroyin yii wọle ti Atoriṣe si n wo ọmọọṣẹ Oluaye lọjọ naa tọpọ awọn oniroyin si wa nita mọju

No comments:

Post a Comment

Pages