Ọpẹ o,papakọ ofurufu ipinlẹ Eko,iṣẹ yoo bẹrẹ nibẹ lọdun yii,ileeṣẹ Adrons ṣi n ta ilẹ nitosi papakọ naa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, January 9, 2024

Ọpẹ o,papakọ ofurufu ipinlẹ Eko,iṣẹ yoo bẹrẹ nibẹ lọdun yii,ileeṣẹ Adrons ṣi n ta ilẹ nitosi papakọ naa


Ìroyin ayọ to balẹ gudẹ fawọn onibara ileeṣẹ Adrons iyen ileese to n ta ile lona irorun lasiko yii ni pe,papako ofurufu tipinle Eko nijoba ti so pe,ile Ibẹju Lekki ti ko jinna si Ẹpẹ ni papakọ naa yoo wa.Kọmiṣọna feto iroyin nipinlẹ Eko,ọgbẹni Gbenga Ọmọtọsọ lo fidi ẹ mule fawọn oniroyin laipẹ yii pe,ọdun yii gan an ni iṣẹ yoo bẹrẹ ni pẹrẹu
Eko city ti ko jina si Rehoboth ni ibeju ni ileeṣẹ ADRONS si ni ilẹ si,to si jẹ pe ẹ le san owo diẹdie nitori nini ibugbe lọna irọrun lo jẹ Aarẹ Emmanuelking to je oludasile ileeṣẹ naa logun
Boya ẹyin fẹ mọ ohunkohun nipa ilẹ ,tabi ẹ fẹ ra ilẹ,ẹ le kan si eyikeyi ileeṣẹ Adrons to ba wa nitosi yin,ẹ ma gbagbe pe ilẹ wa nitosi papakọ ofurufu tijọba ipinlẹ Eko yoo bẹrẹ iṣẹ lori ẹ lọdun yii fun tita nileeṣẹ ADRONS .

No comments:

Post a Comment

Pages