Alaga ijoba ibile Ojokoro nipinle Eko,Hammed Idowu eniti opo eeyan mo si Hid ti ki iko agbaboolu ile wa ku oriire lasiko ti won jawe olubori lojo weside iyen ojo ojoru ose yii nibi idije ere boolu Afcon to n lo lowo ni orile ede Cote d'ivoire.
Hid ti wa so pe inu oun yoo dun ti iko SuperEagle ba le gba ife naa wale,ti o si seleri lati fawon odo lebun lojo sannde ose to n bo leyin ti iko Supereagle ba gba ife naa wale
Hid ni alaga ijoba ibile akoko ti yoo joko wo idije boolu pelu awon odo agbegbe re ni eyi to tumo si pe,ore awon eeyan re ni alaga naa

No comments:
Post a Comment