Ohun to da awon osise ileese Adrons iyen ileese to n ta ile fawon eeyan lona irorun lasiko yii loju ni pe,eeyan gidi ni oludasile ileese naa,Aare Emmanuelking Adetola pelu bo se ran mewa ninu awon osisee re lo si orile ede Tanzania
Irin ajo igbafe yii je ona lati fi mo riri awon osisee re fun ise takuntakun ti won ti se fun itesiwaju ileese naa,ni bayii agbegbe StoneTown ati Nakupenda ni Zanzibar lorile ede Tanzania ni won wa bayii
Ti e o ba gbagbe pe osu die seyin ni Aare Emmanuelking fi erin si enu opo oniroyin nilu Eko nipa fifun won lebun oko ayokele,foonu gidi,ero ifoso,laputoopu,iresi apo apo,adie ati ororo.

No comments:
Post a Comment