Ileeṣẹ Adrons Homes ki awọn onibara wọn ku ayẹyẹ ọdun ololufẹ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, February 15, 2024

Ileeṣẹ Adrons Homes ki awọn onibara wọn ku ayẹyẹ ọdun ololufẹ


Odu ni ileeṣẹ Adrons homes,ti a ba n sọrọ nipa ileeṣẹ alalubarika to ṣe e fọkan tan nipa ilẹ ati ile rira ileeṣẹ yii ni asiwaju,lasiko ayajọ ọdun ololufẹ yii ni ileeṣẹ Adrons n ki awọn onibara wọn ku ọdun bẹẹni wọn n sọ pe,ifẹ nikan lo le mu igbesi aye ẹda dun o dara lati maa fi ifẹ ba ara wa lo lasiko ati lẹyin ọdun falẹntain
Boya ẹyin fẹ mọ nipa ọna lati ra ilẹ ẹ tete lọ si ọfiisi ADRONS to ba wa nitosi yin nitori ileese yii nikan lo se e fokan tan ta ba n soro nipa ile rira

No comments:

Post a Comment

Pages