Liz Anjorin ko jale o,iro ni won pa mo o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, February 6, 2024

Liz Anjorin ko jale o,iro ni won pa mo o


Asiri ti pada tu pe awon onise ibi ti won kan fe ba oruko oseretiata obinrin nni iyen Alaaja Aishat Elizabeth Anjorin je lo wa nidi esun ole jija ti won fi kan an lojo aje monde to koja lo yii ninu oja Idumota nipinle Eko
A gbo pe odun to koja ni Liz lo ra aso ninu soobu kan ni idumota to si je pe akanti oko re lo fi sanwo owo to ku die ko to onduredi taosan,leyin ti Liz kuro ninu oja lojo naa ni banki oko re yo owo yii pada kuro ni akanti iya alaso sugbon ti oko liz,Alaaji Lawal ko so fun Liz rara,eyi lo mu kawon iya alaso pariwo pw liz se alaati feeki fawon lojo ti Liz tun pada de ibe lojo monde to koja
Sa o,awon iya alaso yii ti wa ago oloopa bayii ti won yoo si foju bale ejo laipe fun esun ibanilorukoje sugbon ti eni to ni soobu aso si ti salo ni ti e.

No comments:

Post a Comment

Pages