O mase o?oga ileese banki Access ti ku o,ijamba oko ofurufu lo pa won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, February 10, 2024

O mase o?oga ileese banki Access ti ku o,ijamba oko ofurufu lo pa won


omo bibi ipinle Rivers ni oludasile banki Access,oloogbe Herbert Wigwe sugbon ti iku ti pada da emi e,iyawo e atomo okunrin kan soso ti won bi legbodo lojo satide ninu ijamba oko ofurufu ni agbegbe California ni orileede America
Oga ileese NGX ogbeni Abimbola Ogunbanjo naa wa ninu oko ofurufu yii,adura topo eeyan n gba ni pe ki Olorun tu molebi awon oloogbe ninu

No comments:

Post a Comment

Pages