Yọmi Fabiyi fẹ ṣayẹyẹ onibeji nilu Abẹokuta - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, February 12, 2024

Yọmi Fabiyi fẹ ṣayẹyẹ onibeji nilu Abẹokuta


Gbajumọ oṣeretiata okunrin nni Ọgbẹni Yọmi Fabiyi ti pe awọn ololufẹ ẹ sibi ayẹyẹ onibeji ti yoo ṣe lọjọ kinni oṣu karun un ọdun yii nilu Abẹokuta,yoo ṣile awoṣifila bẹẹni yoo tun ṣayẹyẹ ọjọ ibi ẹ
Alaaji Sule Alao Malaika ni yoo dalubolẹ lọjọ naa

No comments:

Post a Comment

Pages