Ẹgbẹ katakara ilẹ ati ile nipinlẹ Eko iyẹn REDAN ti ṣabẹwo si oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS ,Aarẹ Emmanuelking lojo die seyin nibi ti oludije sipo alaga fun egbe naa nipinle Eko Dokita Segun Oshundairo ti ba Aare Emmanuelking so erongba re fun egbe to ba wole gege bii Alaga egbe
Pelu ayo ati idunnu ni oga ileese ADRONS fi gbalejo dokita Segun atawon eeyan re naa ti o si seleri lati gbaruku ti won nitori ilosiwaju egbe lo je Aare Adetola to tun je Aare Apesinola tilu Ibadan logun
Dokita Segun se opo ileri fun egbe bii,mimu idagbasok ba ipinle re atawon ohun miiran lojo naa ti Aare Adetola si so pe oun wa leyin re pelu atileyin Olorun

No comments:
Post a Comment