Loooto ni ara Obaorin iyen Saheed Osupa le lenu ojo meta yii to si je pe orin ijoko lo ti n korin lati igba to ti de si orile ede yii lati America,sugbon ti asiri ti pada tu pe aisan iba taifoodu lasan lo se alagbede orin,ose meji gbako loba orin lo ni ileewosan kan ni America ki awon dokita ibe to o pase pe ko maa lo sile,leyin eyi ni Jakky pada si orile ede yii
Saturday, March 2, 2024
Aisan iba ponjupoto(Typhoid)lasan lo se Oba orin o
Loooto ni ara Obaorin iyen Saheed Osupa le lenu ojo meta yii to si je pe orin ijoko lo ti n korin lati igba to ti de si orile ede yii lati America,sugbon ti asiri ti pada tu pe aisan iba taifoodu lasan lo se alagbede orin,ose meji gbako loba orin lo ni ileewosan kan ni America ki awon dokita ibe to o pase pe ko maa lo sile,leyin eyi ni Jakky pada si orile ede yii
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment