Daniel Amokachi yoo kopa nibi idije boolu afesegba ileese ADRONS todun 2024 yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, April 23, 2024

Daniel Amokachi yoo kopa nibi idije boolu afesegba ileese ADRONS todun 2024 yii


Agba oje lara awon agbaboolu ile wa nigba kan ri,Daniel Amokachi ti fi idunnu re han pelu bi yoo se wa lara awon agbaboolu ti yoo kopa nibi ifesewonse boolu tileese ADRONS yoo sagbateru e lodun yii,to si je pe Amokachi yoo saaju awon agbaboolu ti yoo kopa fun ileese naa
O soro yii lasiko toun ati oludasile ileese Adrons,Aare Emmanuelking n soro ni olu ileese won to wa nipinle Eko nibe lo ti fi idunnu re han

No comments:

Post a Comment

Pages