Ibrahim Idris omo Gomina ana nipinle Kogi naa tun jade laye leyin to kirun odun itunu awe tan - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, April 10, 2024

Ibrahim Idris omo Gomina ana nipinle Kogi naa tun jade laye leyin to kirun odun itunu awe tan


O ma wa ga bayii o,leyin ti iroyin gba igboro pe Osolo ti Isolo nilu Eko oba Kabiru Agbabiaka waja leyin to de lati yidi nibi ti o ti lo kirun odun niroyin tun gba igboro pe,omo gomina ana nipinle Kogi ,Idris naa tun je ipe Olorun leyin to de lati yidi odun,won ti sinku oloogbe sile ite oku kan nilu Abuja

No comments:

Post a Comment

Pages