Sannde oni yii gan an ni ayajọ ọjọ awọn abiamọ tootọ(Mothers day)ti ileese Adrons iyen ileese to se e fokan tan nipa tita ati rira ile ati ilẹ kaakiri Orilẹ ede yii ti wa n ki awọn mama fun ti ayẹyẹ ọdun wọn to waye lọjọ oni
Adura ti ileeṣẹ ADRONS labẹ Aarẹ Emmanuelking to je oludasile won wa n gba fawon abiamo aye ni pe,Olorun yoo tubo je ki onje omo jinna pe pe fun won,ki won si jere omo.
No comments:
Post a Comment