Egbe PCRC iyen apapo egbe olopaa nipinle Eko ti fi oludasile ileese Adrons iyen ileese to se e fokantan ninu ise ile tita je oye baba isale egbe naa,Aare Adetola Emmanuelking ati iyawo e,Yeye Aderonke ni awon egbe olopaa yii so pe nitori ise ribiribi ti won n se nipa eto aabo ati riri i pe,alaafia n joba lawon agbegbe ti ileese Adrons ba ni ile ati ilẹ si kaakiri Orile ede yii paapaa julo nipinle Eko lo mu egbe PCRC fi oye nla naa ye ogbontarigi omobibi ipinle Ogun da lola
Oga agba egbe ,Alaaji Mogaji Ibrahim Olaniyan wa dupe lowo Aare Emanuelking fun bibowo fun ileese olopaa nibikibi to ba n lo ati pe Apesinola ilu Ibadan yii ki n ko iyan ileese olopaa kere rara
Yeye Aderonke naa ti wa be gbogbo awon olugbe Orile ede yii lati ri olopaa gege bii ore won beeni ki won fowo so wopo pelu ileese olopaa lati gbogun ti iwa odaran lawujo
No comments:
Post a Comment