Ileẹjọ ti pada kede Ọba Yisa Ọlaniyan gẹgẹ bii ojulowo ọba Ipokia lẹyin ọdun kẹrin-in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Friday, June 14, 2024

Ileẹjọ ti pada kede Ọba Yisa Ọlaniyan gẹgẹ bii ojulowo ọba Ipokia lẹyin ọdun kẹrin-in


Adajọ Ogunfowora tile ẹjọ giga kan nilu Abẹokuta ti pada kede Ọba Oluṣọla Yisa Ọlaniyan gẹgẹ bii onipokia tilu Ipokia
O sọ lọjọ naa pe ki idile Aṣade lọ sinmi nipa ẹjọ ti wọn n ro kiri igboro pe ori ade naa ki n ṣe ọba
Adajọ sọ pe idile Aṣade ko si lara awọn 'Iwaye'iyẹn idile ti wọn ti n jọba nilu naa ti ọba Oluṣọla si wa lara idile 'Iwaye Dodo bii oke.
Ju gbogbo e lo,Oba Yisa Olaniyan ni ojulowo oba ipokia nipinle Ogun ti eyi si ti n mu inu opo awon omo bibi ilu naa ni tile toko dun kaakiri

No comments:

Post a Comment

Pages