Ope o ileese ADRONS ṣagbatẹru Ojude ọba Ijẹbu Ode Ọdun yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Friday, June 14, 2024

Ope o ileese ADRONS ṣagbatẹru Ojude ọba Ijẹbu Ode Ọdun yii


Inu iduunu lọpọ awon omo bibi ijebu ode nipinle Ogun wa bayii pelu bii ileese ADRONS iyẹn ileeṣẹ to n ta ilẹ ati ile kaakiri orilẹ ede yii ṣe wa lara ileeṣè to ṣagbatẹru ojude ọba Ijẹbu ode ọdun yii
Ohun to tun wa jẹ kidunnu ṣubu lu ayọ fawọn ti yoo wa nibẹ lọjọ naa ni pe,ileeṣẹ Adrons yoo ṣẹdinwo lori ilẹ ati ile fawọn to ba fẹ ba wọn dowopọ nibi ayẹyẹ ojude ọba ọdun yii
Lasiko ti ipade waye tawọn ọga agba ileeṣẹ naa bii,arabinrin Ajọbọ Adenikẹ,Ọgbẹni Micheal Oyadele,Arabinrin Azuru Ihuoma atawon mi in sepade nipa tita ile lona irorun fawon eeyan nibi ojude oba odun yii ni won ti so o di mimo pe,kawon mekunnu di onile lori lo je oludasile ileese Adrons,Aare Emmanuelking logun idi eyi ni won se gbe eto ile olowo pooku naa wa si ojude oba ijebu ode ti inu Alayeluwa Oba Sikiru Adetona Awujale Ijebu Ode si dun si eto yii pelu

No comments:

Post a Comment

Pages