Oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkantan nipa ilẹ ati ile tita fawọn eeyan lọna irọrun,Aarẹ EmmanuelKing Adetọla ti sọ pe ileeṣẹ oun ṣetan lati ṣagbatẹru ojude ọba ti Ijẹbu ode lọdun yii,o sọrọ yii lasiko to ṣabẹwo si aafin Awujalẹ ọba Sikiru Adetọna Ọgbagba keji nibẹ lo tun ti ṣeleri lati ta ilẹ lowo pooku fawọn ọmọ bibi ilu Ijẹbu kaakiri .
Kabiesi wa dupẹ lọwọ Aarẹ Adetọla bẹẹ lori ade naa ti ṣeleri lati fọwọsowopọ pẹlu ileeṣẹ Adrons ki ohun gbogbo le lọ letoleto
No comments:
Post a Comment