Ẹgbẹ awọn to n ta ilẹ ati ile nipinlẹ Eko ati ilẹ yoruba lapapọ iyẹn ẹgbẹ REDAN ṣabẹwo si oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS,Aare Emmanuel King ,awon agbaagba egbe bii Aare egbe,Omooba Akinloye Adeoye,igbakeji egbe Kunle Adeyemi,akowe egbe,Jide Ogunleye atawon mi in,olu ileese Adrons to wa ni Omole Ipinle Eko ni egbe Redan ti so opo oro ti won si dupe lowo Aare Adetola Emmanuelking fun atileyin re ati bo se n gbiyanju lati je ki opo tenanti di onile lori lona irorun.
Aare Emmanuelking naa dupe lowo egbe Redan fun ifowosowopo won fun itesiwaju egbe naa,bee lo seleri lati tubo maa satileyin fun egbe Redan.
No comments:
Post a Comment