Lati ọdun 2012 ti ileese Adrons ti bere si i ni ta ile ati ilẹ lọna irọrun fawọn onibara rẹ kaakiri origun mẹrẹẹrin Orilẹ ede yii,lo mu ileeṣẹ naa jẹ araba laarin awọn akẹẹgbẹ rẹ,ẹsiteeti to le ni mejidinlogun ni wọn ni kaakiri orilẹ ede yii,ipinlẹ mẹsan ọtọọtọ ni ileeṣẹ yii ti n ṣebi ọba tawọn akẹẹgbẹ rẹ si n wo lokeere.
Eto aabo,ileewe gidi fawọn ogo wẹẹrẹ,ibi igbafẹ,aaye fun ọkọ ayọkẹlẹ,eto ilera,ibi itaja igbalode ,ina ijọba to dara atawọn ohun amayedẹru mi in lo wa ninu awọn ẹsiteeti ileeṣẹ ADRONS kaakiri.
O le sanwo diẹdiẹ to ba fẹ ra ile ati ilẹ lọdọ wọn,kan si ileeṣẹ ADRONS to ba wa ladugbo ẹ,ADRONS araba ni baba
No comments:
Post a Comment