Ko si ẹni to de agbegbe Ṣimawa nipinlẹ Ogun ti wọn ko ni i mọ pe ,iyatọ ti de ba agbegbe naa pẹlu awọn ohun amayedẹrun ti ileeṣẹ ADRONS ,iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkan tan ninu ka ra ilẹ ati ile lọna irọrun.
Ọna to ja geerege,ina ẹlẹtiriiki,koto idominu,ileewe to dara,ibi igbafẹ to dun un wo loju,atawọn ohun amayedẹrun mi in lo wa lawọn ẹsiteeti ileeṣẹ ADRONS.
O ti le ni ọdun mèwa bayii ti ileeṣẹ naa ti n ta ilẹ ati ẹsiteeti lagegbe Ṣimawa ,ti ẹsiteeti marun un to rẹwa ṣi wa nilẹ bayii fun tita
Awọn ẹsiteeti naa ni
*Treasure park and garden phase 2(City of David)
**Treasure park and garden phaze 3(Capetown)
**Treasure park and garden(Jerusalem city)
**Treasure park and garden phaze 4(Extension)
**Treasure park and garden phaze 5(city of God)
Gbogbo awon adugbo yii ni eto aabo wa nibe
Boya eyin nife lati ba ileese Adrons dowopo,e kan si ofiisi won to wa nitosi yin,ileese ADRONS Araba ni baba
No comments:
Post a Comment