Gbogbo ọjọ kejidinlogun oṣu keje ni ayajọ ọjọ ibi obinrin akọkọ nipinlẹ Ogun,Arabinrin Bamidele Abiọdun,ti oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS,Aarẹ Adetọla Emmanuelking si ti n ki iyawo Gomina Abiodun ku ayeye orikadun
Loni in yii gan an ni arewa obinrin naa pe odun mejidinlogota loke eepẹ,ti Aarẹ Adetọla naa si darapọ mọ awọn ẹbi ati ọrẹ gomina lati ba a ṣajọyọ ọjọ ibi iyawo ẹ.
Aarẹ wa dupe lọwọ mama ọlọjọ ibi fun ifọwọsowọpọ rẹ pẹlu gomina fun itẹsiwaju ipinlẹ naa,Olori Bamidele Abiọdun api baide tuuuu yuuuuu ma
Boya ẹyin ṣi fẹ mọ nipa bi ẹ ṣe le ra ilẹ ati ile nileeṣẹ ADRONS,ẹ le kan si ọkan lara ọfiisi wọn to ba wa nitosi yin,ADRONS Araba ni baba nipa ilẹ ati ile tita.
No comments:
Post a Comment