Pelu Ajọ ẹgbẹrun mẹwa nileeṣẹ Adrons ,o le di onile lori - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, July 7, 2024

Pelu Ajọ ẹgbẹrun mẹwa nileeṣẹ Adrons ,o le di onile lori


Ki awọn onibara wọn le di onile lori lo mu ileeṣẹ Adrons iyẹn ileeṣẹ to n ta ile lọna irọrun fawọn onibara wọn gbe eto ajọ dida lọna irọrun kalẹ ,ẹgbẹrun mẹwa naira ni ẹnikẹni to ba nifẹ lati ra ilẹ lọwọ wọn yo ma a da sibẹ titi ti owo naa yoo fi pe,o le kan sileeṣẹ wọn to ba wa nitosi lati di onile lori lọna irọrun

No comments:

Post a Comment

Pages