Aṣíri idi ti ọpọ eeyan ṣe n lọ sileeṣẹ alalubarika ninu iṣẹ ilẹ tita ati rira,ADRONS ni pe,ileeṣẹ yii ni awọn amuyẹ ti ọpọ awọn akẹẹgbẹ rẹ ko ni,yatọ si pe wọn gba san diẹdiẹ owo ,awọn ohun pataki kan wa ti ileeṣẹ yii n ṣe lati mu ki ọna atidi onile lori rọrun fun pupọ eeyan nigboro paapaa lasiko ti orilẹ ede Naijiria dara yii.
Awọn amuyẹ to mu ileeṣẹ ADRONS tayọ ni pe,ẹ le ra ilẹ sawọn igberiko ki ẹ si ma a jaye ọlọba tawọn to wa nigboro n jẹ laisi ariwo tabi inira.Yatọ si eyi ẹ tun le gbadun awọn ohun wọnyii
**Ibi aye nla pelu owo perente,ile to po repete nibikibi ti e ba fe ile si.
**Adugbo to fini lokan bale ati ibugbe irorun.
**Ibugbe ti ife ati ajosepo to danmoran wa pelu awon olubagbe ati akegbe yin
**Ibugbe ati adugbo ti e feran lati gbe ni gbogbo ipinle to wa ni orile ede yii.
**Ko siru ohun amayederu bii,ona geerege,ina monamona,eto aabo to peye ati beebeelo,ti e n wa ti ileese Adrons ko ni i fun yin.
***Idunnu onibara won lo je won logun,won ki n ko iyan onibara won kere rara,iwaju ni ileese Adrons ma n fi oro onibara won si.
***Ko si iye ti e ni lowo ti ileese Adrons ko ni i ta ile fun un yin nitori won gba san diedie.
**Adugbo to te daadaa ati agbegbe to rewa bii ilu oyinbo ni won ni ile si lawon agbegbe igberiko ti yoo si dabi pe ilu oba le wa.
Boya iwo fe mo si i nipa ileese Adrons tabi o fe ba won dowopo,tete maa lo si ofiisi won to ba wa nitosi odo e.ADRONS araba ni baba loooto
No comments:
Post a Comment