Okiki Raji olorin fuji ti joye ojulowo omo nidi fuji - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, September 3, 2024

Okiki Raji olorin fuji ti joye ojulowo omo nidi fuji


Aare Shina Akanni Aroworeyin lo fa owo Okiki Raji to je gbajumo laarin awon olorin fuji soke lose die seyin nibi ayeye'fuji festival 'to waye nipinle Eko
Aroworeyin topo tun mo si Scopido ti wa so pe,Okiki  nikan ni ojulowo omo laarin awon onifuji.
Alaaji Okiki naa ti wa dupe lowo awon agbaagba nidi ise fuji bee lo gba won nimoran pe,ife ati otito lo le tete je ki ise orin fuji de ipo giga.

No comments:

Post a Comment

Pages